ÌWÉ ÒWE 14:29

ÌWÉ ÒWE 14:29 YCE

Ẹni tí kì í báá yára bínú lóye lọpọlọpọ, ṣugbọn onínúfùfù ń fi ìwà òmùgọ̀ rẹ̀ hàn.