ÌWÉ ÒWE 15:28

ÌWÉ ÒWE 15:28 YCE

Olódodo a máa ronú kí ó tó fèsì ọ̀rọ̀, ṣugbọn ọ̀rọ̀ burúkú níí máa jáde lẹ́nu àwọn eniyan burúkú.