ÌWÉ ÒWE 16:32

ÌWÉ ÒWE 16:32 YCE

Ẹni tí kì í tètè bínú sàn ju alágbára lọ, ẹni tí ń kó ara rẹ̀ níjàánu sàn ju ẹni tí ó jagun gba odidi ìlú lọ.