ÌWÉ ÒWE 16:9

ÌWÉ ÒWE 16:9 YCE

Eniyan lè jókòó kí ó ṣètò ìgbésẹ̀ rẹ̀, ṣugbọn OLUWA níí tọ́ ìṣísẹ̀ ẹni.