ÌWÉ ÒWE 17:17

ÌWÉ ÒWE 17:17 YCE

Ọ̀rẹ́ a máa fẹ́ni nígbà gbogbo, ṣugbọn a bí arakunrin láti dúró tini ní ìgbà ìpọ́njú.