ÌWÉ ÒWE 19:17

ÌWÉ ÒWE 19:17 YCE

Ẹni tí ó ṣe ojurere fún àwọn talaka, OLUWA ni ó ṣe é fún, OLUWA yóo sì san ẹ̀san rẹ̀ fún un.