ÌWÉ ÒWE 19:23

ÌWÉ ÒWE 19:23 YCE

Ìbẹ̀rù OLUWA a máa mú ìyè wá, ẹni tí ó ní i yóo ní ìfọ̀kànbalẹ̀, ìṣẹ̀lẹ̀ burúkú kan kò ní ṣẹlẹ̀ sí i.