ÌWÉ ÒWE 20:19

ÌWÉ ÒWE 20:19 YCE

Ẹni tí ó ń ṣe òfófó káàkiri a máa tú ọpọlọpọ àṣírí, nítorí náà má ṣe bá ẹlẹ́jọ́ kẹ́gbẹ́.