ÌWÉ ÒWE 24:17-18

ÌWÉ ÒWE 24:17-18 YCE

Má yọ̀ nígbà tí ọ̀tá rẹ bá ṣubú, má sì jẹ́ kí inú rẹ dùn bí ó bá kọsẹ̀, kí OLUWA má baà bínú sí ọ tí ó bá rí ọ, kí ó sì yí ojú ibinu rẹ̀ pada kúrò lára ọ̀tá rẹ.