ÌWÉ ÒWE 26:27

ÌWÉ ÒWE 26:27 YCE

Ẹni tí ó bá gbẹ́ kòtò, ni yóo já sinu rẹ̀, ẹni tí ó bá sì ń yí òkúta ni òkúta yóo pada yí lù.