ÌWÉ ÒWE 29:15

ÌWÉ ÒWE 29:15 YCE

Pàṣán ati ìbáwí a máa kọ́ ọmọ lọ́gbọ́n, ọmọ tí a bá fi sílẹ̀ yóo dójúti ìyá rẹ̀.