ÌWÉ ÒWE 29:9

ÌWÉ ÒWE 29:9 YCE

Nígbà tí ọlọ́gbọ́n bá pe òmùgọ̀ lẹ́jọ́, ẹ̀rín ni òmùgọ̀ yóo máa fi rín, yóo máa pariwo, kò sì ní dákẹ́.