ORIN DAFIDI 103:12

ORIN DAFIDI 103:12 YCE

Bí ìlà oòrùn ti jìnnà sí ìwọ oòrùn, bẹ́ẹ̀ ni ó mú ẹ̀ṣẹ̀ wa jìnnà sí wa.