ORIN DAFIDI 139:7

ORIN DAFIDI 139:7 YCE

Níbo ni mo lè sá lọ, tí ẹ̀mí rẹ kò ní sí níbẹ̀? Níbo ni mo lè sá gbà tí ojú rẹ kò ní tó mi?