ORIN DAFIDI 62:5

ORIN DAFIDI 62:5 YCE

Ọlọrun nìkan ni mo fi sùúrù gbẹ́kẹ̀lé, nítorí ọ̀dọ̀ rẹ̀ ni ìrètí mi ti wá.