ORIN DAFIDI 65:11

ORIN DAFIDI 65:11 YCE

O mú kí ìkórè oko pọ̀ yanturu ní òpin ọdún; gbogbo ipa ọ̀nà rẹ sì kún fún ọpọlọpọ ìkórè oko.