ORIN DAFIDI 66:20

ORIN DAFIDI 66:20 YCE

Ìyìn ni fún Ọlọrun, nítorí pé kò kọ adura mi; kò sì mú kí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ kúrò lórí mi.