ORIN DAFIDI 68:5

ORIN DAFIDI 68:5 YCE

Baba àwọn aláìníbaba ati olùgbèjà àwọn opó ni Ọlọrun, ní ibùgbé rẹ̀ mímọ́.