ORIN DAFIDI 71:3

ORIN DAFIDI 71:3 YCE

Máa ṣe àpáta ààbò fún mi, jẹ́ odi alágbára fún mi kí o sì gbà mí, nítorí ìwọ ni ààbò ati odi mi.