ORIN DAFIDI 74:12

ORIN DAFIDI 74:12 YCE

Ọlọrun, ìwọ ṣá ni ọba wa láti ìbẹ̀rẹ̀ wá; ìwọ ni o máa ń gbà wá là láàrin gbogbo orílẹ̀-èdè.