ORIN DAFIDI 95:6-7

ORIN DAFIDI 95:6-7 YCE

Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí á jọ́sìn, kí á tẹríba, ẹ jẹ́ kí á kúnlẹ̀ níwájú OLUWA, Ẹlẹ́dàá wa! Nítorí òun ni Ọlọrun wa, àwa ni eniyan rẹ̀, tí ó ń kó jẹ̀ káàkiri, àwa ni agbo aguntan rẹ̀.