ORIN DAFIDI 96:2

ORIN DAFIDI 96:2 YCE

Ẹ kọ orin sí OLUWA, ẹ yin orúkọ rẹ̀; ẹ sọ nípa ìgbàlà rẹ̀ láti ọjọ́ dé ọjọ́.