ORIN DAFIDI 96:3

ORIN DAFIDI 96:3 YCE

Ẹ kéde ògo rẹ̀ láàrin àwọn orílẹ̀-èdè; ẹ sọ̀rọ̀ iṣẹ́ ìyanu rẹ̀ láàrin àwọn eniyan.