ORIN DAFIDI 96:4

ORIN DAFIDI 96:4 YCE

Nítorí OLUWA tóbi, ó yẹ kí á máa yìn ín lọpọlọpọ; ó sì yẹ kí á bẹ̀rù rẹ̀ ju gbogbo oriṣa lọ.