ORIN DAFIDI 99:1

ORIN DAFIDI 99:1 YCE

OLUWA jọba, kí àwọn orílẹ̀-èdè wárìrì; ó gúnwà lórí àwọn kerubu; kí ilẹ̀ mì tìtì.