ÌFIHÀN 2:4

ÌFIHÀN 2:4 YCE

Ṣugbọn mo ní nǹkan wí sí ọ. O ti kọ ìfẹ́ tí o ní nígbà tí o kọ́kọ́ gbàgbọ́ sílẹ̀.