ORIN SOLOMONI 6:10

ORIN SOLOMONI 6:10 YCE

Ta ni ń yọ bọ̀ bí ìmọ́lẹ̀ òwúrọ̀ yìí, tí ó mọ́ bí ọjọ́, tí ó lẹ́wà bí òṣùpá. Tí ó sì bani lẹ́rù, bí àwọn ọmọ ogun tí wọn dira ogun?