ORIN SOLOMONI 6:3

ORIN SOLOMONI 6:3 YCE

Olùfẹ́ mi ló ni mí, èmi ni mo sì ni olùfẹ́ mi. Láàrin òdòdó lílì, ni ó ti ń da ẹran rẹ̀.