ORIN SOLOMONI Ọ̀rọ̀ Iṣaaju
Ọ̀rọ̀ Iṣaaju
Ewì ìfẹ́ ni Orin Solomoni, nítorí ọpọlọpọ orin tí ó wà ninu rẹ̀ jẹ mọ́ ọ̀rọ̀ ìfẹ́ láàrin ọkunrin kan ati obinrin kan tí wọ́n jẹ́ olólùfẹ́. Àwọn ìwé mìíràn pè é ní Orin Solomoni, nítorí pé àwọn Heberu ka ọ̀rọ̀ orin náà kún orin tí Solomoni kọ. Àwọn mìíràn sì ń pè é ní “Orin tí ó dùn jùlọ.”
Àwọn Juu ń fi ojú àjọṣe láàrin Ọlọrun ati àwọn eniyan rẹ̀ wo àwọn orin wọnyi, ṣugbọn ojú àjọṣe láàrin Kristi ati ìjọ ni àwọn Kristẹni fi wò wọ́n.
Àwọn Ohun tí ó wà ninu Ìwé yìí ní Ìsọ̀rí-ìsọ̀rí
Orin kinni 1:1–2:7
Orin keji 2:8–3:5
Orin kẹta 3:6–5:1
Orin kẹrin 5:2–6:3
Orin karun-un 6:4–8:4
Orin kẹfa 8:5-14
Àwon tá yàn lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí:
ORIN SOLOMONI Ọ̀rọ̀ Iṣaaju: YCE
Ìsàmì-sí
Pín
Daako
Ṣé o fẹ́ fi àwọn ohun pàtàkì pamọ́ sórí gbogbo àwọn ẹ̀rọ rẹ? Wọlé pẹ̀lú àkántì tuntun tàbí wọlé pẹ̀lú àkántì tí tẹ́lẹ̀
Bible Society of Nigeria © 1900/2010

: