I. A. Ọba 19:12

I. A. Ọba 19:12 YBCV

Ati lẹhin isẹlẹ na, iná; ṣugbọn Oluwa kò si ninu iná na, ati lẹhin iná na, ohùn kẹ́lẹ kekere.