II. A. Ọba 3:15

II. A. Ọba 3:15 YBCV

Ṣugbọn ẹ mu akọrin kan fun mi wá nisisiyi. O si ṣe, nigbati akọrin na nkọrin, ọwọ Oluwa si bà le e.