A. Oni 16:1

A. Oni 16:1 YBCV

SAMSONI si lọ si Gasa, o si ri obinrin panṣaga kan nibẹ̀, o si wọle tọ̀ ọ.