Owe 16:17-19

Owe 16:17-19 YBCV

Òpopo-ọ̀na awọn aduro-ṣinṣin ni ati kuro ninu ibi: ẹniti o pa ọ̀na rẹ̀ mọ́, o pa ọkàn rẹ̀ mọ́. Igberaga ni iṣaju iparun, agidi ọkàn ni iṣaju iṣubu. O san lati ṣe onirẹlẹ ọkàn pẹlu awọn talaka, jù ati ba awọn agberaga pin ikógun.