O. Daf 137:3-4

O. Daf 137:3-4 YBCV

Nitoripe nibẹ li awọn ti o kó wa ni igbekun bère orin lọwọ wa; ati awọn ti o ni wa lara bère idaraya wipe; Ẹ kọ orin Sioni kan fun wa. Awa o ti ṣe kọ orin Oluwa ni ilẹ àjeji?