Rom 5:3-4

Rom 5:3-4 YBCV

Kì si iṣe bẹ̃ nikan, ṣugbọn awa si nṣogo ninu wahalà pẹlu: bi a ti mọ̀ pe wahalà nṣiṣẹ sũru; Ati sũru nṣiṣẹ iriri; ati iriri ni nṣiṣẹ ireti

Àwọn àwòrán ẹsẹ fún Rom 5:3-4

Rom 5:3-4 - Kì si iṣe bẹ̃ nikan, ṣugbọn awa si nṣogo ninu wahalà pẹlu: bi a ti mọ̀ pe wahalà nṣiṣẹ sũru;
Ati sũru nṣiṣẹ iriri; ati iriri ni nṣiṣẹ ireti