1 Kronika 10:13-14
1 Kronika 10:13-14 BMYO
Saulu kú nítorí kò ṣe òtítọ́ sí Olúwa, kò pa ọ̀rọ̀ Olúwa mọ́ pẹ̀lú, ó tọ abókùúsọ̀rọ̀ lọ fún ìtọ́sọ́nà. Kò sì béèrè lọ́wọ́ Olúwa, bẹ́ẹ̀ ni Olúwapa á, Ó sì yí ìjọba náà padà sọ́dọ̀ Dafidi ọmọ Jese.