1 Ọba 17:16

1 Ọba 17:16 YCB

Nítorí ìkòkò ìyẹ̀fun náà kò ṣófo, kólòbó òróró náà kò gbẹ, gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ OLúWA tí ó ti ipa Elijah sọ.