Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì
Ṣe Àwárí

1 Ọba 8:56

1 Ọba 8:56 BMYO

“Ìbùkún ni fún Olúwa tí ó ti fi ìsinmi fún Israẹli, ènìyàn rẹ̀ bí ó ti ṣèlérí. Kò sí ọ̀rọ̀ rẹ̀ kan tí ó kùnà nínú gbogbo ìlérí rere tí ó ti ṣe láti ọwọ́ Mose ìránṣẹ́ rẹ̀ wá.