2 Ọba 3:11

2 Ọba 3:11 YCB

Ṣùgbọ́n Jehoṣafati sì wí pé, “Ṣé kò sí wòlíì OLúWA níbí, tí àwa ìbá ti ọ̀dọ̀ rẹ̀ béèrè lọ́wọ́ rẹ̀?” Ọ̀kan lára àwọn ìránṣẹ́ ọba Israẹli dáhùn pé, “Eliṣa ọmọ Ṣafati wà níbí. Ó máa sábà bu omi sí ọwọ́ Elijah.”