Ìṣe àwọn Aposteli 12:5

Ìṣe àwọn Aposteli 12:5 YCB

Nítorí náà wọn fi Peteru pamọ́ sínú túbú; ṣùgbọ́n ìjọ ń fi ìtara gbàdúrà sọ́dọ̀ Ọlọ́run fún un.