Ìṣe àwọn Aposteli 18:10

Ìṣe àwọn Aposteli 18:10 YCB

Nítorí tí èmí wà pẹ̀lú rẹ, kò sì sí ẹni tí yóò dìde sí ọ láti pa ọ lára: nítorí mo ní ènìyàn púpọ̀ ni ìlú yìí.”