Sì rántí pé, ìwọ ti jẹ́ ẹrú ní Ejibiti rí, àti pé OLúWA Ọlọ́run rẹ yọ ọ́ kúrò níbẹ̀ pẹ̀lú agbára ńlá, àti nína ọwọ́ rẹ̀. Torí èyí ni OLúWA Ọlọ́run rẹ ṣe pàṣẹ fún ọ láti ya ọjọ́ ìsinmi sí mímọ́.
Kà Deuteronomi 5
Feti si Deuteronomi 5
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: Deuteronomi 5:15
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò