Deuteronomi 8:1

Deuteronomi 8:1 YCB

Ẹ kíyèsi i láti máa tẹ̀lé gbogbo àṣẹ tí mo fún un yín lónìí, kí ẹ bá à le yè, kí ẹ sì pọ̀ sí i wọ ilẹ̀ náà, kí ẹ sì le gba ilẹ̀ náà, tí OLúWA fì búra ṣèlérí fún àwọn baba ńlá a yín.