Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì
Ṣe Àwárí

Eksodu 39:43

Eksodu 39:43 BMYO

Mose bẹ iṣẹ́ náà wò, ó sì rí i wí pé wọ́n ti ṣe é gẹ́gẹ́ bí Olúwati pàṣẹ. Nítorí náà Mose sì bùkún fún wọn.