Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì
Ṣe Àwárí

Eksodu 40:34-35

Eksodu 40:34-35 BMYO

Nígbà náà ni àwọsánmọ̀ bo àgọ́ àjọ, ògo Olúwa bo àgọ́ náà. Mose kò sì lè wọ inú àgọ́ àjọ, nítorí àwọsánmọ̀ wà ní orí àgọ́, ògo Olúwa sì ti kún inú àgọ́ náà.