Esekiẹli 37:1-2

Esekiẹli 37:1-2 YCB

Ọwọ́ OLúWA wà lára mi, ó sì mú mi jáde pẹ̀lú ẹ̀mí OLúWA, ó mú kí ń wà ní àárín àfonífojì; ti o kún fún àwọn egungun. Ó mú mi lọ síwájú àti sẹ́yìn láàrín wọn, èmi sì rí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn egungun ní orí ilẹ̀ àfonífojì, àwọn egungun tí ó gbẹ gan.