Hosea 3:5

Hosea 3:5 YCB

Lẹ́yìn èyí ni àwọn ọmọ Israẹli yóò padà láti wá OLúWA Ọlọ́run wọn àti Dafidi ọba wọn. Wọn yóò sì wá síwájú OLúWA pẹ̀lú ẹ̀rù, wọn ó sì jọ̀wọ́ ara wọn fún OLúWA àti ìbùkún rẹ̀ ní ọjọ́ ìkẹyìn.