Isaiah 17:3

Isaiah 17:3 YCB

Ìlú olódi ni yóò pòórá kúrò ní Efraimu, àti agbára ọba kúrò ní Damasku; àwọn àṣẹ́kù Aramu yóò dá gẹ́gẹ́ bí ògo ti àwọn Israẹli,” ni OLúWA àwọn ọmọ-ogun wí.