Isaiah 19:1

Isaiah 19:1 YCB

Ọ̀rọ̀-ìmọ̀ tí ó kan Ejibiti: Kíyèsi i, OLúWA gun àwọsánmọ̀ tí ó yára lẹ́ṣin ó sì ń bọ̀ wá sí Ejibiti. Àwọn ère òrìṣà Ejibiti wárìrì níwájú rẹ̀, ọkàn àwọn ará Ejibiti sì ti domi nínú wọn.