Isaiah 19:19

Isaiah 19:19 YCB

Ní ọjọ́ náà pẹpẹ kan yóò wà fún OLúWA ní àárín gbùngbùn Ejibiti, àti ọ̀wọ́n kan fún OLúWA ní etí bodè rẹ̀.